Yorùbá and Igbo
orùbá and Igbo 2
Credit: Prof L. O. Adewole
Yoruba for academic purpose
Adé: Ṣé
Òjó lọ ní ọ̀sẹ̀
tí ó kọjá?
Did Ojo leave last
week?
Olú: Rárá, ó ṣẹ̀ṣẹ̀
lọ ni
‘No, he just left
Mbà, o pụrụ
kítáà
Adé: Ǹ jẹ́ o fẹ́ràn ọbẹ̀ ilá?
‘Do you like okro soup?
Òfé
önunö o na-ámásí gí?
Olú: N ò tíì rí òkan rí
‘I
have never seen one before’
Àfúbèghi
m ya na mbú
Adé: Mo
ti ́ń
kọ́
Yorùbá fún ọsẹ̀ méjì
‘I
have been studying Yoruba for two weeks’
M
na-águ Yorùbá kémgbé ízù ukà àbụq
Olú: Mo ti ń kọ́ ọ fún ọdún mẹ́rin
‘I
have been studying it for four years’
M
na-ágú yá kémgbé áfö ànö
Ọnà ilé wa nìyí
‘That’s the way to our house’
Nkè áhu bu uzô ulô ányí
Ọkọ̀ mi nìyí
‘This
is my vehicle’
Nke a bu ugböàlà m
Mo san owó ọkọ mi
‘I
paid my fare/I paid for my vehicle’
M kwùrù ugwö ugböàlà m
Gáráàjì nìyí
‘That is the motor park’
Nkè áhu bú Gáráàjì
Ibùdókô nìyí
‘That is the motor park’
Nkè áhú bu ôdô ugböàlà
Ìdíkô nìyí
‘That is the motor park’
Nkè áhu bu ôdô ugböàlà
Owó ọkọ̀ mi nìyí
‘This
is my fare/This is the money for my vehicle’
Nkéà bu égò ugböàlà m
Èrò púpọ̀ ń wọ ọkọ̀
‘Many passengers are
entering the vehicle’,
Ötutu ndí njém na-ábànye
n’imé ugböàlà ahu
Agbèrò ni Olú
‘Olu is a motor park tout’
Olú bu ónyé agbòrò
Dírẹ́bà ni Dèjì
‘Deji is a driver’
Dèjì bu dìrívá
Awakô ni Dèjì
‘Dèjì is a driver’
Dèjì bu ónyé ôkpö ugböàlà
Bọ́ọ̀sì yìí tóbi
‘This bus is big’
Bọọsù a bùrù íbù
Káà yìí kéré
‘This car is small’
ugböàlà a pèrè mpé
Mo wa tasín lánàá
‘I took a taxi yesterday’
M bàrà tákuzí ùyàà
A dé ibùdókọ̀ rélùwéè
‘We reached the railway station’
Ányí rùrù rélúwéè
A gba tíkẹ́ẹ̀tì wa
‘We bought out ticket’
Ányí gòtèrè tíkéètì ányí
A wọ rélùwéè
‘We board a train’
Ányí bàlu túwénù
Adé lọ sí ibùdókọ̀ òfurufú
‘Adé went to the airport’
Adé gara ọdọ úgbóélú
Ó wọ ọkọ̀ òfurufú
‘He boards a plane’
Ọ bara úgbóélú
Comments
Post a Comment