SOME ASPECTS OF LINGUISTIC ANALYSIS OF ỌKÙNRIN YẸPẸRẸ
SOME ASPECTS OF LINGUISTIC ANALYSIS OF ỌKÙNRIN YẸPẸRẸ
Credit: Prof L. O. Adewole
Yoruba for academic purpose
Kí ló ṣe yín o?[1]
Ẹ̀yin ọkùrin yẹpẹrẹ abààbọ̀ ìlẹ̀kẹ̀ ní fùrọ̀
Mo ṣe bí ibi tó le là á bọ́kùrin ni
Yẹtí ṣe détí, ẹ̀gbá ̣se dọ́rùn?
Ohun obìin ṣe dápá?
Nítorí oge àkínyẹ́sín
Ẹ tún ń jórun níná
Ẹ ò sì rọra; èyí mà pọ̀ ọ̀
Ojú ò mà rírú èyí nígbà ayé baba wa
Ẹ ní ẹ̣ tún féẹ́ ̣lo àpamọ́wó?
Mo ṣe bọ́mọge la ṣe é fún ni?
O tún rè é gbé e, ìwọ ọkùnrin oníyẹ̀yẹ́
Oníyẹ̀yẹ́, oníyẹ́ẹ́rí
Lọ́fíndà tún nùun, nnkan àrà gbáà
Ẹ ò sọ pé ẹ ò níí bayé jẹ́ fáráyé
Ẹ fẹ́ẹ́ yẹ nǹkan mó ẹsẹ̀ kan soso táyé fí tilẹ
Kò ma níí pẹ́ tẹ́ ̣ẹ ó fi máa kun tojú kun tẹnu!
DELETION
V¹ + V² = V¹ + V1
or V² + V2
Examples of this process that
can be seen in the above poem are shown below;
ni + ó = li ó = ló………………………….line 1
tí + ó = tí ó = tó………………………….line 3
bá + ọkùnrin = bá ọkùnrin = bọ́kùnrin…..line 3
dé + etí = dé etí = détí…………………...line 4
dé + ọrùn = dé ọrùn = dọ́run…………….line 4
dé + apá = dé apá = dápá………………..line 5
jó + irun = jó irun = jórun……………….line 7
rí + irú = rí irú = rírú…………………….line 9
ní + ìgbà = ní ìgbà = nígbà……………....line 9
bí + ọmọge = bí ọmọge = bọ́mọge………line11
tí + ayé = tí ayé = táyé…………………...line 16
ti + ilẹ̀ = ti ilẹ̀ = tilẹ……………………....line 16
ti + ojú = ti ojú = tojú…………………….line 17
ti + ẹnu = ti ẹnu = tẹnu…………………..,line 17
Declarative Sentence
This type of sentence is
basically used to make a statement.
Ẹ̀yin ọkùrin yẹpẹrẹ abààbò ìlẹ̀kẹ̀ ní fùrọ̀……line 2
Ẹ tún ń jórun níná……………………………line 7
Interrogative
Sentence
This type of sentence is used to
ask questions. And some of its examples as seen in the poem are;
Mo ṣe bí ibi tó le là á bọ́kùrin ni…………line 3
Yetí ṣe détí, ẹ̀gbá ṣe dọ́rùn?.......................line
4
Ohun obìin ṣe dápá………………………line 5
Emi ẹ tún ti fẹ́ẹ́ ṣe àpamọ́wọ́?...................line 10
Mo ṣe bọ́mọge la ṣe é fún ni?.....................line 11
Exclamatory Sentence
This is a sentence that shows
strong emotions. Example of this can be found in the poe
Example
Kò ma níí pẹ́ tẹ́ ẹ ó fi máa kun tojú kun tẹnu!......line
17
[1] Adesina Ifeluwa Peter analysed this poem.
Comments
Post a Comment