Hausa/Yoruba: Òǹkà (Number-Words)
Hausa/Yoruba: Òǹkà (Number-Words)
Credit: Prof L. O. Adewole
Yoruba for academic purpose
Daya - ení
- (one)
Biyu - èjì - (two)
Uku - ẹ̀ta - (three)
Hudu - ẹ̀rin - (four)
Biyar - àrún -
(five)
Shida - ẹ̀fà - (six)
Bakwai - èje - (seven)
Takwas - ẹ̀jọ - (eight)
Tara - ẹ̀sán - (nine)
Goma - ẹ̀wá - (ten)
Goma sha
daya - oókànlá
- (eleven)
Goma sha
biyu - eéjìlá
- (twelve)
Goma sha uku - ẹẹ́tàlá
- (thirteen)
Goma sha hudu - ẹẹ́rìnlá
- (fourteen)
Goma sha
biyar - aárùndínlógún - (fifteen)
Goma sha
shida - ẹẹ́rìndínlógún
- (sixteen)
Goma sha
bakwa - ẹẹ́tàdínlógún
- (seventeen)
Goma sha takwas - eéjìdínlógún
- (eighteen)
Goma sha
tara - oókàndínlógún - (nineteen)
Ashirin - oogún/okòó - (twenty)
Ashirin da
daya - oókànlélógún
- (twenty-one)
Ashirin da
biyu - eéjìlélógún
- (twenty-two)
Ashirin da
uku - ẹẹ́tàlélógún - (twenty-three)
Ashirin da
hudu - ẹẹ́rìnlélógún
- (twenty-four),
Ashirin da
biyar - aárùndínlọ́gbọ̀n
- (twenty-five)
Ashirin da
shida - ẹẹ́rìndínlọ́gbọ̀n
- (twenty-six)
Ashirin da bakwai - ẹẹ́tàdínlọ́gbọ̀n - (twenty-seven)
Ashirin da takwas - eéjìdínlọ́gbọ̀n - (twenty-eight)
Ahirin da
tara - oókàndínlọ́gbọ̀n - (twenty-nine)
Talatin - ọgbọ̀n - (thirty).
Talatin da
daya - oókànlélọgbọ̀n - (thirty-one)
Talatin da biyu - eéjìlélọgbọ̀n - (thirty-two)
Talatin da
uku - ẹẹ́tàlélọgbọ̀n - (thirty-three)
Talatin da
hudu - ẹẹ́rìnlélọgbọ̀n - (thirty-four)
Talatin da biyar
- aárùndínlógójì - (thirty-five)
Talatin da
shida - ẹẹ́rìndínlógójì - (thirty-six)
Talatin da bakwai - ẹẹ́tàdínlógójì
- (thirty-seven)
Talatin da
takwas - eéjìdínlógójì - (thirty-eight)
Talatin da
tara - oókàndínlógójì - (thirty-nine)
Arba’in - ogójì - (forty)
Arba’in da
daya - oókànlélógójì - (forty-one)
Arba’in da
biyu - eéjìlélógójì - (forty-two)
Arba’in da
uku - ẹẹ́tàlélógójì - (forty-three)
Arba’in da
hudu - ẹẹ́rìnlélógójì - (forty-four)
Arba’in da
biyar - aárùndínláàádọ́ta - (forty-five)
Arba’in da
shida - ẹẹ́rìndínláàádọ́ta - (forty-six)
Arba’in da
bakwai - ẹẹ́tàdínláàádọ́ta - (forty-seven)
Arba’in da
takwas - eéjìdínláàádọ́ta - (forty-eight)
Arba’in da
tara - oókàndínláàádọ́ta - (forty-nine)
Comments
Post a Comment