Edo and Yoruba
Edo and Yoruba
Credit: Prof L. O. Adewole
Yoruba for academic purpose
Ení (one)
Owo
Èjì (two)
Eva
Ẹ̀ta
(three)
Eha
Ẹ̀rin (four)
Enẹ
Àrún (five)
Isen
Ẹ̀fà (six)
Ehan
Èje (seven)
Ihinron
Ẹ̀jọ (eight)
Erenren
Ẹ̀sán (nine)
Ihinrin
Ẹ̀wá (ten)
Igbe
Oókànlá (eleven)
Owọrọ
Eéjìlá (twelve)
Iweeva
Ẹẹ́tàlá (thirteen)
Iweeha
Ẹẹ́rìnlá (fourteen)
Iweenẹ
Aárùndínlógún (fifteen)
Ekesugie
Ẹẹ́rìndínlógún (sixteen)
Eneirrọ̣vbugie
Ẹẹ́tàdínlógún (seventeen)
Ehairrọvbugie
Eéjìdínlógún (eighteen)
Evairrọvbugie
Oókàndínlógún (nineteen)
Okpairrọvbugie
Oogún/okòó (twenty)
Ugie
Oókànlélógún (twenty-one)
Okpa-yan-ugie
Eéjìlélógún (twenty-two)
Eva-yan-ugie
Ẹẹ́tàlélógún
(twenty-three)
Eha-yan-ugie
Eẹ́rìnlélógún (twenty-four)
Enẹ-yan-ugie
Aárùndínlọ́gbọ̀n (twenty-five)
Isen-yan-ugie
Ẹẹ́rìndínlọ́gbọ̀n (twenty-six)
Eneirrọvbọgban
Ẹẹ́tàdínlọ́gbọ̀n (twenty-seven)
Ehairrọvbọgban
Eéjìdínlọ́gbọ̀n (twenty-eight)
Evairrọvbọgban
Oókàndínlọ́gbọ̀n (twenty-nine)
Ọkpairrọvbọgban
Ọgbọ̀n
(thirty)
Ọgban
Oókànlélọgbọ̀n (thirty-one)
Ọkpa-yan-ọgban
Eéjìlélọgbọ̀n (thirty-two)
Eva-yan-ọgban
Ẹẹ́tàlélọgbọ̀n
(thirty-three)
Eha-yan-ọgban
Ẹẹ́rìnlélọgbọ̀n (thirty-four)
Enẹ-yan-ọgban
Aárùndínlógójì (thirty-five)
Isen-yan-ọgban
Ẹẹ́rìndínlógójì (thirty-six)
Enẹirrọvbiyeva
Ẹẹ́tàdínlógójì (thirty-seven)
Ehairrọvbiyeva
Eéjìdínlógójì (thirty-eight)
Evairrọvbiyeva
Oókàndínlógójì (thirty-nine)
Ọkpairrọvbiyeva
Ogójì (forty)
Iyeva
Oókànlélógójì (forty-one)
Ọkpa-yan-iyeva
Eéjìlélógójì (forty-two)
Eva-yan-iyeva
Ẹẹ́tàlélógójì
(forty-three)
Eha-yan-iyeva
Ẹẹ́rìnlélógójì
(forty-four)
Enẹ-yan-iyeva
Aárùndínláàádọ́ta (forty-five)
Isen-yan-iyeva
Ẹẹ́rìndínláàádọ́ta (forty-six)
Enẹirrọvbekigbesiyeha
Ẹẹ́tàdínláàádọ́ta (forty-seven)
Ehairrọvbekigbesiyeha
Eéjìdínláàádọ́ta (forty-eight)
Evairrọvbekigbesiyeha
Oókàndínláàádọ́ta (forty-nine)
Ọkpairrọvbekigbesiyeha
Àádọ́ta (fifty)
Ekigbesiyeha
Oókànléláàádọ́ta (fifty-one)
Ọkpa-yan-ekigbesiyeha
Eéjìlẹ́láàádọ́ta (fifty-two)
Eva-yan-ekigbesiyeha
Ẹẹ́tàléláàádọ́ta (fifty-three)
Eha-yan-ekigbesiyeha
Ẹẹ́rìnléláàádọta (fifty-four)
Enẹ-yan-ekigbesiyeha
Aárùndinlógọ́ta (fifty-five)
Isen-yan-ekigbesiyeha
Ẹẹ́rìndìnlọ́gọ́ta (fifty-six)
Enẹirrọvbiyeha
ẹ́tàdínlọ́gọ́ta (fifty-seven)
Ehairrọvbiyeha
Eéjìdínlógọ́ta (fifty-eight)
Evairrọvbiyeha
Oókàndínlọ́gọ́ta (fifty-nine)
Ọkpairrọvbiyeha
Ọgọ́ta (sixty)
Iyeha
Oókànlélọ́gọ́ta (sixty one)
Ọkpa-yan-iyeha
Eéjìlélọ́gọ́ta (sixty-two)
Eva-yan-iyeha
Ẹẹ́tàlélọ́gọ́ta (sixty-three)
Eha-yan-iyeha
Ẹẹ́rìnlélọ́gọ́ta (sixty-four)
Enẹ-yan-iyeha
Aárùndìnláàádọ́rin (sixty five)
Isen-yan-iyeha
Ẹẹ̀rindínláàádọ́rin (sixty-six)
Enẹirrọvbekigbesiyene
Ẹẹ́tàdìnláàádọrin (sixty-seven)
Ehairrọvbekigbesiyene
Eéjìdínláàádọ́rin (sixty-eight)
Evairrọvbekigbesiyene
Oókàndínláàádọ́rin (sixty-nine)
Ọkpairrịvbekigbesiyene
Àádọ́rin (seventy)
Ekigbesiyenẹ
Oókànléláàádọ́rin (seventy-one)
Ọkpa-yan-ekigbesiyenẹ
Eéjìléláàádọ́rin (seventy-two)
Eva-yan-ekigbesiyenẹ
Ẹẹ́tàléláàádọ́rin (seventy-three)
Eha-yan-ekigbesiyenẹ
Ẹẹ́rínléláàádọ́rin (seventy-four)
Enẹ-yan-ekigbesiyene
Aárùndínlọ́gọ́rin (seventy-five)
Isen-yan-ekigbesiyenẹ
Ẹérìndìnlọ́gọ́rin (seventy-six)
Enẹirrọvbiyenẹ
Ẹẹ́tàdìnlógọ́rin (seventy-seven)
Ehairrọvbiyenẹ
Eéjìdínlọ́gọ́rin (seventy-eight)
Evairrọvbiyenẹ
Oókàndínlọ́gọ́rin (seventy-nine)
Ọkpairrọvbiyenẹ
Ọgọ́rin (eighty)
Iyenẹ
Oókànlélọ́gọ́rin (eighty –one)
Ọkpa-yan-iyenẹ
Eẹ́jìlélọ́gọ́rin (eighty-two)
Eva-yan-iyenẹ
Ẹẹ́tàlélọ́gọ́rin (eighty-three)
Eha-yan-iyenẹ
Ẹẹ́rìnlélọ́gọ́rin (eighty-four)
Enẹ-yan-iyenẹ
Ààrúndínláàádọ́rùn-ún (eighty-five)
Isen-yan-iyenẹ
Ẹẹ́rìndínláàádọrùn-ún
(eighty-seven)
Enẹirrọvbekigbesiyisen
Ẹẹ́tàdínláàádọ́rùn-ún
(eighty-seven)
Ehairrọvbekigbesiyisen
Eéjìdínláàádọ́rùn-ún (eighty-eight)
Evairrọvbekigbesiyisen
Oókàndínláàádọ́rùn-ún (eighty-nine)
Ọkpairrọvbekigbesiyisen
Àádọ́rùn-ún (ninety)
Okigbesiyisen
Oókànléláàádọ́run-ún (ninety-one)
Ọkpa-yan-ekigbesiyisen
ẹẹ́jìlél’aàádó.run-ún (ninety-two)
Eva-yan-ekigbesiyisen
Ẹẹ́tàléláàádọ́rùn-ùn (ninety-three)
Eha-yan-ekigbesiyisen
Eẹ́rìnléláàdọ́rùn-ún (ninety four)
Enẹ-yan-ekigbesiyisen
Aárùndínlọ́gọ́rùn-ún (ninety five)
Isen-yan-ebigbesiyisen
Ẹérìndínlọ́gọ́rùn-ún (ninety six)
Enẹirrọvbiyisen
Ẹẹ́tàdínlọ́gọ́rùn-ún (ninety seven)
Ehairrọvbiyisen
Eéjìdínlọ́gọ́rùn-ún (ninety eighty)
Evairrọvbiyisen
Oókàndínlọ́gọ́ọ̀rún (ninety nine)
Ọkpairrọvbiyisen
Ọgọ́rún-ún (one hundred)
Iyisen
Àròpọ̀ (+)
Ama Orhieha
Ìyọkúrò (-)
Ama Orhieyo
Ìsọdipúpọ̀ (x)
Ama Oghae
Àárọ̀ (morning)
Owie
Ọ̀sàn (afternoon)
Avan
Ìrọ̀lẹ́ (evening)
Ota
Alẹ́ (night)
Ason
Kú àárọ̀ (good morning)
Obowie
Kú ọ̀sán (good afternoon)
Obavan
Kú ìrọ̀lẹ́ (good evening)
Obota
Ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn (dry season)
Uyunmwun
Ìgbà òjò (rainy season)
Orhọ
Ìlà-oòrùn (east)
Eken
Ìwọ̀-oòrùn (west)
Orie
Gúúsù (south)
Ahọ
Àríwá (north)
Okuo
Comments
Post a Comment