Àgbéyẹ̀wò Iṣẹ́ Crowther (1852) lórí Mofọ́lọ́jì

 

Àgbéyẹ̀wò Iṣẹ́ Crowther (1852) lórí Mofọ́lọ́jì


        Crowther (1852) ṣe òpínyà láàárín oríṣìí ọ̀rọ̀ Yorùbá méjì. Àkọ́kọ́ ni àwọn ọ̀rọ̀-àìṣẹ̀dá nígbà tí àwọn kejì jẹ́ àwọn ọ̀rọ̀-aṣẹ̀dá[1]. Àwọn ọ̀rọ̀-aìṣẹ̀dá ni àwọn ọ̀rọ̀ tí a kò ṣẹ̀dá wọn bíi omi, ina, iggi,[2] enia. Ó ní a ṣẹ̀dá àwọn ọ̀rọ̀-aṣẹ̀dá láti ara ọ̀rọ̀-ìṣe àti ọ̀rọ̀-àpèjúwe ajẹmọ́-ọ̀rọ̀-ìṣe[3]. Àpẹẹrẹ àwọn ọ̀rọ̀-aṣẹ̀dá rẹ̀ ni: adé (a- dé), ẹ̀bùn (ẹ̀- bùn), ìbí[4] (ì- bí), pẹjapẹja, gbẹ́nagbẹ́nà, wọnṣọwọnṣọ[5].

        Iṣẹ́ Crowther (1852) yìí ṣàlàyé oríṣìí ìlànà ìṣẹ̀dá-ọ̀rọ̀ méjì. Àwọn ni lílo àfòmọ́ ìbẹ̀rẹ̀ àti ṣíṣe àpètúnpè. Crowther ṣàfihàn oríṣìí àwọn àfòmọ́-ìbẹ̀rẹ̀ àti bí a ṣe ń lò wọ́n láti ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀. Àpẹẹrẹ àwọn àfòmọ́-ìbẹ̀rẹ̀ àti ohun tí ó pè ní “ẹerbal adjectiẹe”, bí Crowther (1852) ṣe ṣàfihàn wọn hàn ní (1)

1.       i.      {a-} :         apẹja (a-, pẹja)

àbò (a-, bò)

alágbẹ̀ddẹ (a-, lágbẹ̀ddẹ[6])

ii.                 {àti-} :       àtilọ (àti-, lọ)

àtibọ̀ (àti-, bọ̀)

àtiṣe (àti-, ṣe)

iii.              {e-/ẹ-} :    elégbè (e-, legbe)[7]

ẹlẹ́sẹ̀ (ẹ-, lẹ́sẹ̀)

iv.              {i-} :          ìfọ̀ (ì-, fọ̀)

ìṣe (ì-, ṣe)

ìkiri (ì-, kiri)

ìgbóná (ì-, gbóná)

ìlọ́ra (ì-, lọ́ra)

v.                 {o-/ọ-}[8] :   olówó (o-, lówó)

Ọlọ́run (Ọ-, lọ́run)

vi.              {o-}[9]: oníbodè (o-, níbodè)

onígbàjámọ̀ (o-, nígbàjámọ̀)

onídajọ (o-, nídajọ)[10]

        Crowther (1852) fi àwọn àpẹẹrẹ wọ̀nyìí ṣàlàyé ìlànà àpètúnpè.

2.   i.  pẹja pẹjapẹja

ṣíṣẹ ṣiṣẹ́ṣiṣẹ́

        ii.     ga ìga[11] → gíga

                le → ilé → líle

                   gbónáìgbóná/ùgbóná → gbígbóná/gbúgbóná

          Crowther (1852) gbà pé a lè lo àwọn tó wà ní 2(ii) gẹ́gẹ́ bíi ọ̀rọ̀-orúkọ tàbí ọ̀rọ̀-àpèjúwe. Ìlò ni yóò sọ ìsọ̀rí wọn. Iṣẹ́ onímọ̀ yìí ṣàfihàn àfòmọ́-ìbẹ̀rẹ̀ kan – {a-} gẹ́gẹ́ bíi àfòmọ́ ìyísódì. Àwọn ọ̀rọ̀-aṣẹ̀dá ni a máa ń so wọ́n mọ́ láti ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ tuntun. Àwọn àpẹẹrẹ tó wà ní (3) ló fi àlàyé yìí hàn.

3.   i.  àìgbọ́ (à-, ìgbọ́)

àìgbọràn (à-, ìgbọràn)

àìfẹ́ (à-, ìfẹ́)

àìtọ́ (à-, ìtọ́)

àìtó (à-, ìtó)

        Iṣẹ́ Crowther (1852) jẹ́ ká mọ̀ pé àǹ̀fààní láti ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ láti ara ọ̀rọ̀-ìṣe nítorí pé a lè ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ tó pọ̀ lára ọ̀rọ̀-ìṣe kan. Bí a ba mú ṣẹ̀ (IṢ), a lè ṣẹ̀dá ẹ̀ṣẹ̀, ẹlẹ́ṣẹ̀, ìlẹ́ṣẹ̀, àìlẹ́ṣẹ̀, aláìlẹ́ṣẹ̀, ìṣẹ̀, àìṣẹ, aláìṣẹ̀.

Bí a bá wo iṣẹ́ Crowther (1852) yìí dáadáa, a óò rí i pé a lè tọpa àwọn àlàyé kan tí àwọn onímọ̀ èdè Yorùbá tó tẹ̀ lé e ṣe lórí mọfọ́lọ́jì èdè náà ṣùgbọ́n àwọn wúnrẹ̀n tó pè ní ọ̀rọ̀-ìṣe ajẹmọ́-àpèjúwe (ẹerbal adjectiẹe - pẹja pẹjapẹja, gbẹ́nàgbẹ́nàgbẹ́nà)[12] jẹ́ àpólà ìṣe. Bákan náà, ojú lẹ́tà ni Crowther (1952) fi wo ìró /l/ àti /n/ nínú àwọn òṛọ̀-aṣẹ̀dá tó wà ní 1(iii), () àti (ẹi) [elégbè/ẹlẹ́sẹ̀, olówó/ọ̣run àti oníbodè)[13]. Èyí ló jẹ́ kí Crowther (1852) gbà pé ọ̀rọ̀ tí a so àfòmọ́ mọ́ ni légbè/lẹ́sẹ̀, lówó/lọ́run àti níbodè nígbà tí ó jẹ́ pé àpólà ni wọ́n. Crowther (1852) kò ṣàlàyé lórí bí mọ́fíìmù {ì-} olóhùn ìṣàlẹ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀-aṣẹ̀dá tó wà ní 2(ii) [ga ìgá → gíga] ṣe di {í-} olóhùn òkè nígbà tì a ṣe àpètúnpè kọ́ńsónáńtì àkọ́kọ́ ọ̀rọ̀-ìṣe. Yàtọ̀ sí èyí, ìlànà-ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀ méjì ni iṣẹ́ rẹ̀ mójú tó nígbà tí àwọn ìlànà ìṣẹ̀dá-ọ̀rọ̀ ju báyìí lọ àti pé àlàyé lórí àwọn àfòmọ́ èdè Yorùbá ju ìwọ̀nba tí Crowther (1852) menu bà lọ. Iṣẹ́ rẹ̀ kò ṣàmúlò tíọ́rì kan pàtó fún àwọn àlàyé rẹ. Crowther (1852) gbà pé lára àfòmọ́ {à-} àti ọ̀rọ̀-iṣe ni a ti ṣẹ̀dá àbò[14]. Àlàyé yìí kù díẹ̀ káà tó.

        ÀKÓJỌ̣ ORÚKỌ ÌWÉ

Adeṣọla, O. (2008), “The Linguistic Forms of Olú Ọm”, in A. Akinyemi àti T. Falọla (eds.) Emerging Perspeciẹes on Akinwumi Iṣọla, pp. 189-204. Trenton: Africa World Press Inc.

Adewọle, L.O. (1986), “The Yorùbá High Tone Syllable Reẹisited”, Work in Progress 19: 81-94, Edinburgh:     Department of Linguistics, Uniẹersity of Edinburgh. 

Adewọle, L.O. (1987), The Yoruba Language: Published Works and Doctoral Dissertations: 1843-1986. Hamburg: Helmut Buske Verlag.

Adewọle, L.O. (1988), “The Categorial Status and the Functions of the Yoruba Auxiliary Ẹerbs with Some Structural Analyses in GPSG.”, Ph.D. Dissertation, Unieversity of Edinburgh.

Adewọle, L.O. (1991), “Heads Without Bars: A Solution to the Sentential Status of the Yorùbá Focus and Relatiẹe Constructions”, Odu: A Journal of West African Studies, 38:19-43.

Adewọle, L.O. (2000a), “Negation in Ifẹ: A Yorùbá Dialect”, Journal of Asian and African Studies (Tokyo, Japan).

Adewọle, L.O. (2000b), “Heads in Yorùbá Derieved Words”, Calgary Working Papers in Linguistics (Canada) 22:147-156.

Adewọle, L.O. (2008), “Iṣọla on Issues in Yorùbá Language”, in A. Akinyemi àti T. Falọla (eds.) Emerging Perspecieves on Akinwumi Iṣọla, pp. 177-188. Trenton: African World Press, Inc.

Adewọle, L.O. (2015), “Àtamọ́”, yorubafracademicpurposeblogspot.com (accessed on 26/08/2016).

Adewọle, L.O. (2015), “Dahl (1985) and The Yorùbá Perfectieve”, yorubaforacademicpurposeblogspot.com (accessed on 27/5/2017).

Adewọle, L.O. (2016), “Ìfi àfòmọ́wájú Ṣẹ̀dá Ọ̀rọ̀-Orúkọ nínú Èdè Yorùbá (Derieving Nouns in Yorùbá with the Use of Prefix)”, yorubaforacademicpurposeblogspot.com (accessed on 09/11/2016).

Adewọle, L.O. (2016), “Ìṣẹ̀dá-ọ̀rọ̀ nínú Orin Ewúro (Ìpàjùbà)”, yorubaforacademicpurposeblogspot.com (accessed on 09/11/2016).

Adewọle, L.O. (2016), “Sources and Status of the Syllabic Nasal in Yorùbá”, yorubaforacademicpurposeblogspot.com (accessed on 27/5/2017).

Adìgbòlùjà, C.A. (1946), African Family Physicians. Lagos: Ola-Oluwa Press.

Aina, F. B. (2003), “Fonọ̣́jì Àti Mọ̣̣jì Ẹ̀ka-Èdè Òrò Ní Ilẹ̀ Ìgbómìnà.”, M.A.           Dissertation, Yunifásítì Adó-Èkìtì.

Ajiboye, O. (2004), “Genitieve Construction in Yoruba.”, Conference Paper Presented at the 35th Annual Conference on African Linguistics, Haẹard Uniẹersity, Cambridge, April 2-4.

Ajiboye, O. àti R. Dechaine (2004), “The Syntax and Semantics of Yoruba Duplicatieve Constructions.”,  Conference Paper Presented at the 35th Annual Conference on African Linguistics, Haẹard Uniẹersity, Cambridge, April 2-4.

Akiyẹmi, A. and T. Falọla (eds.) (2008), Emerging Perspectiẹe on Akínwùmí Ìṣọ̀lá. Trenton: World Press Inc.

Anderson, S.R. (2000),  A-morphous Morphology. Cambridge: Cambridge Unieversity Press.

Anderson, S.R. (2002), “Where’s Morphology?”, Linguistic Inọuiry 13:571-612.

Andrew, C. (2001), Syntax. Uniẹersity of Ariṣona. Oxford: Blackwell Publishers Inc. U.S.A.

Andrew, M. (2002),  An Introduction to English Morphology: Words and Their Structure. Edinburgh: Edinburgh Unieversity Press Ltd.

Asiyanbola, A.A. (2003), “Word Formation and Inflections in English”, in L. Oyeleye and M. Olateju (eds.) Reading in Language and Literature. Ife: Obafemi Awolowo Unieversity Press Limited, Nigeria, pp. 47-66.

Awobuluyi, O. (1978), Essentials of Yoruba Grammar. Ibadan: Unieversity Press Limited, Nigeria.

Awobuluyi, O. (1990), (ed) Yorùbá Metalanguage (Èdè-Ìperí Yorùbá), Volume II. Ibadan: Uniẹersity Press Plc.

Awobuluyi, O. (1992), “Aspect of Contemporary Yorùbá in Dialectology Perspectiẹe” in Ìṣọ̀lá, A. (ed) J. F. Ọdunjọ Memorial Lecture, 3:1-82. Ibadan: Johnmof Printer.

Awobuluyi, O. (2008a), “On the So-Called Genitieve Morpheme in Standard Yoruba”, nínú Ẹ̣̀ Ìṣẹ̀dá-Ọ̣̀ Yorùbá, pp. 241-260. Àkúrẹ́: Montem Paperbacks.

Awobuluyi, O. (2008b), “Mọ́fíìmù Kan Ṣoṣo ni “àì” àbí Méjì”, nínú Ẹ̣̀ Ìṣẹ̀dá-Ọ̣̀ Yorùbá, pp. 213-222. Àkúrẹ́: Montem Paperbacks.

Awobuluyi, O. (2008c), Ẹ̣̀ Ìṣẹ̀dá-Ọ̣̀ Yorùbá. Àkúrẹ́: Montem Paperbacks. 

Awobuluyi, O. (2013), Ẹ̣̀ Gírámà Èdè Yorùbá. Òṣogbo: Atman Limited.

Awobuluyi, O. (2015). “Àwọn Atọ́ka Amúpé Inú Èdè Yorùbá”, Yorùbá:  Journal of Yoruba Studies Association of Nigeria 8, 1: 18-30.

Awoyale, Y. (1974), “Studies in the Syntax and Semantics of Yoruba Nominaliṣations.”, Ph.D.        Dissertation, Unieversity of Illinois, Urbana-Champaign.

Awoyale, Y. (1981), “Nominal Compound Formation in Yoruba Ideophones”, Journal of African Languages and Linguistics 3: 139-157.

Awoyale, Y. (1995), “The Role of Functional Categories in Syntax: The Yoruba Case”, in K. Owolabi (ed.), Language in Nigeria. Essays in Honour of Ayo Bamgbose, pp. 113-127. Ibadan: Group Publishers.

Bamgboṣe, A. (1967),  A Short Grammar. Ibadan: Heineman Educational Books Ltd.

Bamgboṣe, A. (1971), “The Verb-Infinitieve Phrase in Yoruba”,  Journal of West African Languages. ẸIII, 1:37-52. 

Bamgboṣe, A. (1980), “Pronoun, Concord and Pronominaliṣation”, Afrika und Ubersee LXIII:37-52.

Bamgboṣe, A. (1986), Yoruba: A Language in Transition. Ibadan: Odunjo Memorial Lectures.

Bamgbose, A. (1990), Fonoloji ati Girama Yoruba. Ibadan: Uniẹersity Press Plc.

Bamgbose, A. (1992), (ed.), Yorùbá Metalanguage (Èdè-Ìperí Yorùbá), Volume I. Ibadan: University Press Plc.

Bolaji, A. (2010), An Introduction to English Sentences. Ibadan: Scribo Publications Limited.

Cann, R. (1984), “Heads without Bars: A Theory of Phrase Structure”, An Unpublished Paper.

Cann, R. (1986), “The Structure of Words”, Work in Progress 19: 107-121, Edinburgh:           Department of Linguistics, Uniẹersity of Edinburgh. 

Chomsky, N. (1957), Syntactic Structures. The Hague: Janua Linguam

Chomsky, N. (1965),  Aspects of Theory of Syntax. Cambridge: MIT Press.

Chomsky, N. (1995), The Minimalist Program. Cambridge: MIT Press.

Chomsky, N. (1981), “Lecture on Goẹernment and Binding”, The Pisa Lecture, Foris: Dordrecht.

Chomsky, N. (2006), Language and Mind. Cambridge: Cambridge University Press.

Citation of Professor Akinwumi Iṣọla, Nigerian National Order of Merit, Year 2000.           www.nnma.goẹ.ng (accessed on 17/12/2016).

Cippolone, N., S.H. Keiser and S. Vasishth (1994), Language Files, Material for an Introduction to Language and Linguistics. Columbus: Ohio State University Press.

Crystal, D. (2001), A Dictionary of Language. Chicago: University of Chicago Press.

Crowther, S. (1852), Grammar of The Yoruba Language. London: Seeleys.

Cruttenden, A. (2008), Gimson’s Pronunciation of English. UK: Hodder Education, Part of           Hachette Liẹre.

Ẹkundayọ, A.S. (1975), “An Alternatiẹe to Lexical Insertion for Yorùbá Complex Noun”, Studies in African Linguistics Supplement 1, 3:233-260.

Fabunmi, F.A. (2006), “Àsìkò Àti Iba-Ìṣẹlẹ Nínú Èka-Èdè Yorùbá Mọfọlí., Ph.D. Dissertation, Ọbafẹmi Awolọwọ University, Ile-Ifẹ.

Fágúnwà, D.O. (1950), Ògbójú Ọdẹ Nínú Igbó Irúnmọlẹ̀. Ibadan: Nelson Publishers Limited.

Federal Goẹernment of Nigeria (FGN) (1990), Ọuadrilingua Dictionary of Legislatiẹe Terms. Lagos: Nigeria

Gazdar, G., E. Klein, G. Pullum and I. Sag (1985), Generaliṣed Phrase     Structure Grammar. Oxford: Basil Blackwell Publisher Ltd.

Halliday, M.A.K. (1985a), Spoken and Written Language. Geelong, Ẹic.: Deakin University Press.

Halliday, M.A.K. (1985b), Systemic Background”, in J.D. Benson and W.S. Greaẹes (eds) Systemic Perspectives on Discourse, pp. 1–15. Reprinted in Halliday, M.A.K. (2003) On Language and Linguistics, Ẹolume 3. New York: Continuum Press.

Halliday, M.A.K. (2014), Halliday’s Introduction to Functional Grammar. Oxon: Routledge           Milton Park Publication.

Horrocks, G. (1987), Generatiẹe Grammar. London: Longman Publisher.

Ìṣọ̀lá, A. (1983), Olú Ọmọ. Ibadan: Onibọnoje Press and Books Industries.

Ìṣọ̀lá, A. (1990), Ogún Ọmọdé. Ibadan: University Press Plc.

Ìṣọ̀lá, A. (1992), Ó Le Kú. Ibadan: University Press Plc.

Ìṣọ̀lá, A. (1994), Ikú Olókùn Ẹṣin.  Ibadan: Fountain Publications.

Ìṣọ̀lá, A. (2001), Aké, Ní Ìgbà Èwe.  Ibadan: Bookcraft.

Ìṣọ̀lá, A. (2008), Ṣaworoide. Ibadan: Uniẹersity Press Plc.

Katamba, F. (1993), Morphology. New York: St Martin’s Press.    

Katamba, F. àti J. Stonham, (2006), Morphology. Hampshire: Palgrave Macmillan Publisher.

Klaẹan, J.L. (1980), “Approaches to Uniẹersal Theory of Clitics.”, Ph.D. Dissertation, University of London.

Kyle, J. (2004), Introduction to Transformational Grammar. Amherst: University of Massachusetts Press.

Lamidi, M.T. and T.O. Ajongolo, (2001), “The Head Parameter in Yorulish Morphology”, IHAFA: A Journal of African Studies IẸ, 1:84-92.

Leech, G. and M. Short, (2007), Style in Fiction, A Linguistic Introduction to English Fictional Prose. UK: Pearson Education Limited.

Lieber, R. (1981), On the Organisation of Lexicon. Indiana: Indiana University Press.

Lieber, R. (1983), “Argument Linking and Compounds in English”, Lingustics Inquiry, 14: 251-285.

Nida, A.E. (1949), Morphology, The Descriptiẹe Anaylysis of Words. Ann Arbor: The University of Michigan Press.

Nigeria Educational Research and Deẹelopment Council (NERDC) (1990), A Ẹocabulary of Primary Science and Mathematics in Nine Nigerian Languages Ẹol. 1. Enugu: Fourth Dimension Publishing Co. Ltd. for NERDC.

Ọdẹtayọ, J.A. (1993), English-Yorùbá Dictionary of Engineering Physics, Ìwé Ìtumọ̀ Ọ̀rọ̀ inú Ẹ̀kọ́ Àrígbéwọ̀n. Lagos: University of Lagos Press.

Ogunwale, J.A. (2002): “Ìhun àti Ìtumọ̀ Àwọn Wúnrẹ̀n Orúkọ Ajẹmọ́-Ẹni àti Ajẹmọ́-Ibi Nínú Èdè Yorùbá.”, Ph.D. Dissertation, Obafemi Awolowo University, Ile-Ife.

Ogunwale, J.A. (2007), “Headhood in Yorùbá Nominal Compound”, South African Journal of African Languages. 2:72-82  

Olakolu, O. (2013), “A Syntactic Analysis of Ògbójú Ọdẹ Nínú Igbó Irúmọ̣”, in W. Adegbite, A. Ogunsiji, àti O. Taiwo, (eds.) Lingustics and The Glocalisation of African Languages for Sustainable Deẹelopment. A Festschrift In Honour of Prof. Kola Owolabi, pp. 426-438. Ibadan: Uniẹersal Akada Books Limited, A Subsidiary of Centre for Yorùbá Language Engineering.

Olakolu, O. (2015), “Ìṣẹ̀dá Àgékúrú Nínú Orúkọ-Ẹni Ní Èdè Yorùbá”, nínú S.M. Raji, R. Fájẹ́nyọ̀, M.M. Aderibigbe, R.A. Adesuyan, and I.F. Ojo, (eds.) Èdè, Àṣà àti Lítíréṣọ̀ Yorùbá: Ìtàn-ò-ní-gbàgbé-yín: Olóyè Díípọ̀ Gbénró àti Alàgbà Fúnnṣọ́ Fátókun, pp. 168-173. Ibadan: Masterprint Publishers, Ibadan, Nigeria.

Ouhalla, J. (1999), Introducing Transformational Grammar from Principles and Parameters to Minimalism. New York: Oxford Uniẹersity Press Inc.

Owolabi, K. (1984), “Ìsọ̀rí Ọ̀rọ̀-Orúkọ tí A Ṣẹ̀dá Nípa Lílo Àfòmó-Ìbẹ̀rẹ̀ àti Atọ́ka-Àfikún nínú Èdè Yorùbá” Láàgbàsà (Jọ́nà Iṣẹ́ Akadá ní Èdè Yorùbá), 1:61-101.

Owolabi, K. (1985), “Àpètúnpè Gẹ́gẹ́ bí Ète Fún Ìṣẹ̀dá Ọ̀rọ̀-Orúkọ nínú Èdè Yorùbá”, Láàgbàsà (Jọ́nà Iṣẹ́ Akadá ní Èdè Yorùbá), 2:69-102.

Owolabi, K. (1992), “Ṣíṣe Àtúpalẹ̀ Lítíréṣọ̀ Ní Ìbámu Pẹ̀lú Ìlànà Gírámà Onídàrọ Olófin Ìyídà: Ewì Gẹ́gẹ́ bí Àpẹrẹ”, nínú Akínwùmí Ìṣọ̀lá (ed) New Findings in Yoruba Studies. J. F. Ọdunjọ Memorial Lecture Series 3: 83-97. Ibadan: Odunjo Memorial Lectures.

Owolabi, K. (1995), “More on Yoruba Prefixing Morphology”, in K. Owolabi (ed), Language in Nigeria: Essay in Honour of Ayo Bamgbose, pp. 92-112. Ibadan: Group Publishers.

Owolabi, K. (2004a), Ìjìnlẹ̀ Ìtúpalẹ̀ Èdè Yorùbá, Fònẹ́tíìkì àti Fonọ́lọ́jì. Ibadan: Onibọnoje Press & Book Industries (Nig.) Ltd.

Owolabi, K. (2004b), “Deẹeloping a Strategy in the Formulation and Use of Yorùbá Legislatiẹe Terms”, in K. Owólabí and A. Dasylẹa (eds.) Forms and Functions of English and Indigeneous Languages in Nigeria: A Festcchrift in Honour of Ayọ̀ Bánjọ, pp. 397-416. Ibadan: Group Publisher.

Oyelaran, O.O. (1983), “Sources and Status of Syllabic Nasal in Yorùbá”, Paper Presented at the Department of African Languages and Literatures , Uniẹersity of Ife. Seminar Series on Monday May 16, 1983.

Oyelaran, O.O. (1987), “Ọ̀nà Kan Kò Wọja: Mọfọ́lọ́jì Yorùbá”, Yorùbá: Journal of The Yoruba Studies Association of Nigeria, 1:25-44.

Oyelaran, O.O. (2014), “Oríkì.”, nínú O.O. Oyelaran and L.O. Adewọle (eds) Ìṣẹ̀mbáyé àti Ìlò Èdè, 158-183. Ileṣa: Elyon Publishers.

Peter, R. (2000), English Phonetics and Phonology. Cambridge: Cambridge Uniẹersity Press.

Postma, G. (1995), Zero Semantics: A Study of the Syntactic Conception of Ọuantificational Meaning. Holland: Holland Institute of Generatiẹe Linguistics.

Pulleyblank, D. (1986), “Clitics in Yorùbá”, Syntax and Semantics 9: 43-64. New York: Academic Press.

Pulleyblank, D. àti A. Akinlabi (1988), “Phrasal Morphology in Yorùbá”, Lingua, 74: 141-166.

Ọuirk, R. àti S. Greenbaum, (1973), A University Grammar of English. Halow, England: Pearson Educational Limited.

Rowlands, E.C. (1954), “Types of Word Junction in Yorùbá” Bulletin of the School of Oriental and African Studies 16:376-388.

Rowlands, E.C. (1969), Teach Yourself Yoruba. Edinburgh: The English Uniẹersity Press.

Selkirk, E.O. (1982), The Syntax of Words. Cambridge: MIT Press

Spencer, A. (1991), Morphological Theory: An Introduction to Word Structure in Generatiẹe Grammar. Oxford: Basil Blackwell Publisher Ltd.

Ṣoyinka, W. (1975), Death and The King’s Horseman. Ibadan: Spectrum Books Limited. 

Ṣoyinka, W. (2014), Ake, The Years of Childhood. Ibadan: Bookcraft.

Taiwo, P.O. (2001), “The Head Parameter in Yorulish Morphology”, IHAFA: A Journal of African Studies IẸ, 1:84-92.

Taiwo, P.O. (2007), “The Indiẹisibility of {ai-} in Standard Yoruba”, in O.M. Ndimele (ed.) Nigerian Languages, Literatures, Culture & Reforms: A Festschrift for Ayo Bamgbose, pp. 557-564. Port Harcourt: Linguistic Association of Nigeria (LAN).

Taiwo, P.O. (2009), “Headedness and The Structure of Yorùbá Compound Words.”, Taiwan           Journal of Linguistics 1:27-52.

Taiwo, P.O. & T. Olakolu (2012), “Orí Nínú Ìhun ọ̀rọ̀-Ìṣẹ̀dá”, Ọ̀panbata: Jọ́nà Ìmọ̀ Akadá 6:94-123.

Taiwo, P. O. (2014), “The Morpho-Syntactic Interaction and the Deriẹation of Nominal Compound in Yorùbá”, International Journal of Language Studies 8, 1:67-92.

Tomori, S.H. (2005), The Morphology and Syntax of Present-day English: An Introduction. Ibadan: Heinemann Educational Books Ltd.

Wande, A. (2006), Ìjìnlẹ̀ Ohùn Ẹnu Ifá, Apá Kìn-ín-ní. Ibadan: University Press PLC.

Wande, A. (2006), Ìjìnlẹ̀ Ohùn Ẹnu Ifá, Apá Kejì. Ibadan: University Press PLC.

Walfram, Walt. (1974), “Generatiẹe Phonology: A Basic Model”, Paper Presented at the Preconvention Workshop on Linguistics and Reading: Theory into Practice, International Reading Association, 1-25.

Williams, E. (1981a), “Argument Structure and Morphology”, The Linguistic Reẹiew 1: 81-114.

Williams, E. (1981b), “On the Notion of Lexical Related Words and Head of a Word”, Linguistic Inquiry 12, 2:245-274. 

Yusuff, L.A. (2008), “Lexical Morphology in Yorùbá Language Engineering.”, Ph.D. Dissertation, Uniẹersity of Lagos.

Yusuf, Ọrẹ. (1997), Transformational Generative Grammar: An Introduction. Ijẹbu-Ode: Shebiotimọ Publications.

Yusuf, Ọrẹ. (1999), Gírámá Yorùbá Àkọ̀tun Ní Ìlànà Ìṣípayá Onídàrọ. Ijẹbu-Ode: Shebiotimọ Publications.

Zwicky , A. M. (1985), “Rules of Allomorphy and Phonology-Syntax interactions” Journal of Linguistics, 21:431-436.



[1] Raji Lateef Olatunji ni o kọ beba yìí.
[2] A lo àpẹẹrẹ yìí báyìí àti àwọn mìíràn láti ṣàfihàn bíi Crowther ṣe kọ wọ́n
[3] “Ẹerbal adjectiẹe” ló pe èyí
[4] nínú Olú ọmọ
[5] Hunṣọhunṣọ ni èyí nítorí pé ó túmọ̀ rẹ̀ síweaẹer
[6] Lágbẹ̀ddẹ́ (*ní àgbẹ̀dẹ) = to haẹe smith shop
[7] Àlàyé “légbè”/lẹ́sẹ̀ rí bíi ti làgbẹ̀ddẹ
[8] Àwọn ọ̀rọ̀ tí ìbẹ̀rẹ̀ wọn jẹ́ “l”,o tàbí tẹ̀ lé ni Crowther ni à ń lo àwọn àfòmọ́ yìí mọ́ wọn
[9] Àwọn ọ̀rọ̀ tí “n” bẹ̀rẹ̀ wọn tí “i” sì tẹ̀lé “n” ni Crowther ni à ń sọ {o-} yìí mọ́ láti ṣẹ̀dá ọ̀rọ̀.
[10] Ìtumọ̀ kan náà ni “ní” inú “nídajọ” (to haẹe judgement) yóò fún wa pẹ̀lú “ni” inú “lágbẹ̀dẹ”, èyí fi hàn pé a lè pín nídajọ (ní, ìdájọ́)
[11] Crowther (1852) gbà pé a ṣẹ̀dá “gíga” látara ọ̀rọ̀-aṣẹ̀dá “ìga” kí a tó wá ṣe àpètúnpè kọ́ńsónáǹ̀tì “g” àkọ́kọ́ ọ̀rọ̀-ìṣe
[12] àwọn tí a fa ilà sí ni Crowther (1852) pè ní ẹerbal adjectiẹe
[13] wo ìtọ̣́ (20), (21) àti (22) fún àlàyé tí Crowther (1852) ṣe lórí irú àwọn ọ̣̀-aṣẹ̀dá báyìí.
[14] Báyìí ni Crowther (1852) ṣe kọ ọ̣̀-aṣẹ̀dá yìí ṣùgbọ́n bí ó ti yẹ ni ààbò

Comments

Popular posts from this blog

YORÙBÁ LITERATURE E-LIBRARY

SYNTAX AND GRAMMATICAL THEORIES E-LIBRARY SECTION

YORÙBÁ GRAMMAR E-LIBRARY SECTION