Àgbéyẹ̀wò Iṣẹ́ Ajíbóyè àti Dechaine (2004) lórí àpètúnpè
Àgbéyẹ̀wò Iṣẹ́ Ajíbóyè àti Dechaine (2004)
Ajíbóyè àti
Dechaine (2004) ṣàlàyé lórí àwọn ọ̀rọ̀-aṣẹ̀dá alápètúnpè àti bí ìhun àti
ìtumọ̀ wọn ṣe jẹ mọ́ ìrísí wọn[1].
Iṣẹ́ yìí ṣàlàyé pé a máa ń ṣe àpètúnpè sí àwọn ọ̀rọ̀-orúkọ Yorùbá láti
ṣẹ̀dá afọ̀ ajẹmọ́ye (quantificational expressions) oníhun OR-(X)-OR.
Irú èyí ni à ń pè ní ẹ̀hun alápètúnpè (wo Postma 1995). Ajíbóyè àti Dechaine (2004) ṣàlàyé pé tí a bá fi ojú ìtumọ̀ wò ó, oríṣìí ìhun mẹ́rin ni àwọn irú ọ̀rọ̀
báyìí máa ń ní ṣùgbọ̀n mẹ́ta ni iṣẹ́ yìí gbé yẹ̀ wò nínú wọn. Àwọn ni:
a. ìhun
ajẹmọ́ye káríayé (àsìkò/òǹ̀kà): OR-OR
b. ìhun ajẹmọ́ye onífọ̀n-ọ́n-ká: (OR-OR, OR-de-OR,
OR-kan- OR, OR-lù-OR, OR-ko-OR)
d. Wúnrẹ̀n
alójúlódì (polarity item): OR-kí-OR
e. Ìhun
afòtédè nínú ọ̀rọ̀ (lexically restricted forms): OR-mọ́-OR, OR-ní-OR, OR-bí-OR, OR-rè-OR.
Àlàyé fún ìtumọ̀ àwọn ìhun (a-d) lọ báyìí pé:
i.
Tí
a bá jẹ́ [OR-OR] tó ní ọ̀rọ̀-orúkọ ajẹmásìkò tàbí
òǹ̀kà, ọ̀kan nínú àwọn ọ̀rọ̀-orúkọ yìí jẹ́ àpètúnpè sí èkejì, [ORATP OR], a óò rí ìtumọ̀ “gbogbo” nínú ORATP(ÀTÚNPÈ) (ọ̀rọ̀
ajẹmọ́ye kárí-ayé – collective universal quantification).
ii. ọ̀sọ̀ọ̀sán, ẹ̀tẹ̀ẹ̀ta
(mẹ́tẹ̀ẹ̀ta, mẹ́ta mẹ́ta)
ii.
Tí a bá jẹ́ [OR-X-OR],
X lè jẹ́ ọ̀kan nínú {kàn, kò, lù tàbí dé} nígbà tí ọ̀kan nínú àwọn
ọ̀rọ̀-orúkọ méjì yìí jẹ́ àtúnpè èkejì [ORATP OR], a óò rí ìtumọ̀ “ọ̀kọ̀ọ̀kan”
(each) nínú ORATP (ọ̀rọ̀ ajẹmọ́ye kárí-ayé aláàfọ́nká – distributive universal quantification).
a. ẹgbẹẹgbẹ́ [-eniyan], àgbààgbà [+eniyan]
ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́ [ọwọ́wẹwọ – reciprocal],
ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ [àpọ́nlé]
b.
ẹnukonu [-kan-], ojúkojú [-ko-]
d.
okodóko
[-de-], ìrandíran [-de-]
iii.
Tí a bá jẹ́ [OR-kí-OR],
nígbà tí ọ̀rọ̀-orúkọ kan jẹ́ àtúnpè èkejì, [ORATP-kí-OR], a óò rí
ìtumọ̀ “èyíkéyìí” (any) nínú ORATP (wúnrẹ̀n ajẹmọ́ òdì – negative polarity item)
Tí a bá fi ojú ìtumọ̀ tí àwọn wúnrẹ̀n tí wọ́n jẹ́ àpètúnpè ní wò wọ́n, Ajíbóyè àti
Dechaine (2004) ṣàlàyé pé irú àwọn wúnrẹ̀n tó ń jẹ yọ gẹ́gẹ́ bí àtúnpè nínú
ọ̀rọ̀-aṣẹ̀dá alápètúnpè lè jẹ́ oríṣìí wúnrẹ̀n mìíràn nínú àwọn èdè
kan (wo (a) ní ìsàlẹ̀ fún àpẹẹrẹ), wọ́n
sì lè jẹ́ àkóónú àtúnpè ọ̀rọ̀-orúkọ (wo (b)
ní ìsàlẹ̀ fún àpẹẹrẹ).
a. i. [ỌP [Ọ
all] [DP [D the] [NP students]]]
ii. [ỌP
[Ọ eẹery] [DP [D Æ]
[NP students]]]
b. i. [ỌP
[Ọ alẹ́]
[DP [D Æ] [NP
alẹ́]]] (>alaalẹ́)
ii. [ỌP [Ọ ẹ̀ta] [DP [D Æ] [NP ẹ̀ta]]] (>ẹ̀tẹ̀ẹ̀ta)
ÀTÚNPÈ
ẹ̀ta
Bí a bá wo iṣẹ́ Ajíbóyè àti Dechaine
(2004) yìí, a óò rí i pé ọ̀kan nínú àwọn ìlànà ìṣẹ̀dá ọ̀rọ̀-orúkọ ni ó jẹ mọ́.
Bákan náà, àwọn ọ̀rọ̀ tí ọ̀rọ̀-orúkọ tí a túnpè lè gbé jáde gẹ́gẹ́ bíi ìtumọ̀
náà jẹ yọ níbẹ̀. Iṣé yìí dára gan-an ni.
ÀKÓJỌPỌ̀ ORÚKỌ ÌWÉ
Adeṣọla, O. (2008), “The Linguistic
Forms of Olú Ọmọ”, in A. Akinyemi àti T. Falọla (eds.) Emerging
Perspeciẹes on Akinwumi Iṣọla, pp.
189-204. Trenton: Africa World Press Inc.
Adewọle, L.O. (1986), “The Yorùbá High
Tone Syllable Reẹisited”, Work in Progress 19: 81-94, Edinburgh: Department of Linguistics, Uniẹersity of
Edinburgh.
Adewọle, L.O. (1987), The Yoruba
Language: Published Works and Doctoral Dissertations: 1843-1986. Hamburg:
Helmut Buske Verlag.
Adewọle, L.O. (1988), “The Categorial
Status and the Functions of the Yoruba Auxiliary Ẹerbs with Some Structural
Analyses in GPSG.”, Ph.D. Dissertation, Unieversity of Edinburgh.
Adewọle, L.O. (1991), “Heads Without
Bars: A Solution to the Sentential Status of the Yorùbá Focus and Relatiẹe
Constructions”, Odu: A Journal of West African Studies, 38:19-43.
Adewọle, L.O. (2000a), “Negation in
Ifẹ: A Yorùbá Dialect”,
Journal of Asian and African Studies (Tokyo, Japan).
Adewọle, L.O. (2000b), “Heads in
Yorùbá Derieved
Words”, Calgary Working Papers in Linguistics (Canada) 22:147-156.
Adewọle, L.O. (2008), “Iṣọla on Issues in Yorùbá Language”,
in A. Akinyemi àti T. Falọla
(eds.) Emerging Perspecieves on
Akinwumi Iṣọla, pp.
177-188. Trenton: African World Press, Inc.
Adewọle, L.O. (2015), “Àtamọ́”, yorubafracademicpurposeblogspot.com (accessed on 26/08/2016).
Adewọle, L.O. (2015), “Dahl
(1985) and The Yorùbá Perfectieve”, yorubaforacademicpurposeblogspot.com
(accessed on 27/5/2017).
Adewọle, L.O. (2016), “Ìfi
àfòmọ́wájú Ṣẹ̀dá Ọ̀rọ̀-Orúkọ nínú Èdè Yorùbá (Derieving Nouns in Yorùbá with the Use of Prefix)”, yorubaforacademicpurposeblogspot.com
(accessed on 09/11/2016).
Adewọle, L.O. (2016),
“Ìṣẹ̀dá-ọ̀rọ̀ nínú Orin Ewúro (Ìpàjùbà)”, yorubaforacademicpurposeblogspot.com
(accessed on 09/11/2016).
Adewọle, L.O. (2016), “Sources
and Status of the Syllabic Nasal in Yorùbá”, yorubaforacademicpurposeblogspot.com
(accessed on 27/5/2017).
Adìgbòlùjà,
C.A. (1946), African Family Physicians. Lagos: Ola-Oluwa Press.
Aina, F. B. (2003), “Fonọ́lọ́jì Àti Mọfọ́lọ́jì Ẹ̀ka-Èdè Òrò Ní Ilẹ̀ Ìgbómìnà.”, M.A. Dissertation, Yunifásítì Adó-Èkìtì.
Ajiboye, O. (2004), “Genitieve
Construction in Yoruba.”, Conference Paper Presented at the 35th
Annual Conference on African Linguistics, Haẹard Uniẹersity, Cambridge, April
2-4.
Ajiboye, O. àti R.
Dechaine (2004), “The Syntax and Semantics of Yoruba Duplicatieve Constructions.”, Conference Paper Presented at the 35th Annual
Conference on African Linguistics, Haẹard Uniẹersity, Cambridge, April 2-4.
Akiyẹmi, A. and
T. Falọla (eds.) (2008), Emerging Perspectiẹe on Akínwùmí Ìṣọ̀lá.
Trenton: World Press Inc.
Anderson, S.R. (2000), A-morphous Morphology. Cambridge:
Cambridge Unieversity
Press.
Anderson, S.R. (2002), “Where’s
Morphology?”, Linguistic Inọuiry 13:571-612.
Andrew, C. (2001), Syntax. Uniẹersity of Ariṣona. Oxford:
Blackwell Publishers Inc. U.S.A.
Andrew, M. (2002), An Introduction to English Morphology:
Words and Their Structure. Edinburgh: Edinburgh Unieversity
Press Ltd.
Asiyanbola, A.A. (2003), “Word
Formation and Inflections in English”, in L. Oyeleye and M. Olateju
(eds.) Reading
in Language and Literature. Ife: Obafemi Awolowo Unieversity
Press Limited, Nigeria, pp. 47-66.
Awobuluyi, O. (1978), Essentials of
Yoruba Grammar. Ibadan: Unieversity
Press Limited, Nigeria.
Awobuluyi, O. (1990), (ed) Yorùbá
Metalanguage (Èdè-Ìperí Yorùbá), Volume II.
Ibadan: Uniẹersity Press Plc.
Awobuluyi, O. (1992), “Aspect of
Contemporary Yorùbá in Dialectology Perspectiẹe” in Ìṣọ̀lá, A. (ed) J. F. Ọdunjọ Memorial Lecture, 3:1-82.
Ibadan: Johnmof Printer.
Awobuluyi, O. (2008a), “On the So-Called
Genitieve
Morpheme in Standard Yoruba”, nínú Ẹ̀kọ́ Ìṣẹ̀dá-Ọ̀rọ̀ Yorùbá, pp.
241-260. Àkúrẹ́:
Montem Paperbacks.
Awobuluyi, O. (2008b), “Mọ́fíìmù Kan Ṣoṣo ni “àì” àbí Méjì”, nínú Ẹ̀kọ́ Ìṣẹ̀dá-Ọ̀rọ̀ Yorùbá, pp.
213-222. Àkúrẹ́:
Montem Paperbacks.
Awobuluyi, O. (2008c), Ẹ̀kọ́ Ìṣẹ̀dá-Ọ̀rọ̀ Yorùbá.
Àkúrẹ́: Montem Paperbacks.
Awobuluyi, O. (2013), Ẹ̀kọ́ Gírámà Èdè Yorùbá. Òṣogbo: Atman Limited.
Awobuluyi, O. (2015). “Àwọn Atọ́ka Amúpé Inú Èdè Yorùbá”, Yorùbá: Journal of Yoruba Studies Association of
Nigeria 8, 1: 18-30.
Awoyale, Y.
(1974), “Studies in the Syntax and Semantics of Yoruba Nominaliṣations.”, Ph.D. Dissertation,
Unieversity of Illinois, Urbana-Champaign.
Awoyale, Y. (1981), “Nominal
Compound Formation in Yoruba Ideophones”, Journal of African Languages and
Linguistics 3: 139-157.
Awoyale, Y. (1995), “The Role of
Functional Categories in Syntax: The Yoruba Case”,
in K. Owolabi (ed.), Language in Nigeria. Essays in Honour of Ayo
Bamgbose, pp. 113-127. Ibadan: Group
Publishers.
Bamgboṣe, A. (1967), A Short Grammar. Ibadan: Heineman Educational
Books Ltd.
Bamgboṣe, A. (1971), “The Verb-Infinitieve
Phrase in Yoruba”, Journal of West
African Languages. ẸIII, 1:37-52.
Bamgboṣe, A. (1980), “Pronoun, Concord
and Pronominaliṣation”, Afrika und Ubersee LXIII:37-52.
Bamgboṣe, A. (1986), Yoruba: A Language in Transition. Ibadan: Odunjo Memorial Lectures.
Bamgbose, A. (1990), Fonoloji
ati Girama Yoruba. Ibadan: Uniẹersity Press Plc.
Bamgbose, A. (1992), (ed.), Yorùbá
Metalanguage (Èdè-Ìperí Yorùbá), Volume I. Ibadan: University
Press Plc.
Bolaji, A. (2010), An
Introduction to English Sentences. Ibadan: Scribo Publications Limited.
Cann, R. (1984), “Heads without
Bars: A Theory of Phrase Structure”, An Unpublished Paper.
Cann, R. (1986), “The Structure
of Words”, Work in Progress 19: 107-121, Edinburgh: Department of Linguistics, Uniẹersity
of Edinburgh.
Chomsky, N.
(1957), Syntactic Structures. The Hague: Janua Linguam
Chomsky, N.
(1965), Aspects of Theory of Syntax.
Cambridge: MIT Press.
Chomsky, N.
(1995), The Minimalist Program. Cambridge: MIT Press.
Chomsky, N.
(1981), “Lecture on Goẹernment and Binding”, The Pisa Lecture, Foris:
Dordrecht.
Chomsky, N.
(2006), Language and Mind. Cambridge: Cambridge University Press.
Citation of
Professor Akinwumi Iṣọla, Nigerian National Order of Merit, Year 2000.
www.nnma.goẹ.ng
(accessed on 17/12/2016).
Cippolone, N., S.H. Keiser and S. Vasishth (1994), Language Files, Material for an Introduction to Language
and Linguistics. Columbus: Ohio State University Press.
Crystal, D. (2001), A Dictionary of Language. Chicago: University of Chicago Press.
Crowther, S.
(1852), Grammar of The Yoruba Language. London: Seeleys.
Cruttenden, A.
(2008), Gimson’s Pronunciation of English. UK: Hodder Education, Part of
Hachette Liẹre.
Ẹkundayọ, A.S.
(1975), “An Alternatiẹe to Lexical Insertion for Yorùbá Complex Noun”, Studies
in African Linguistics Supplement 1, 3:233-260.
Fabunmi, F.A.
(2006), “Àsìkò Àti Iba-Ìṣẹlẹ Nínú Èka-Èdè Yorùbá Mọfọlí.”, Ph.D.
Dissertation, Ọbafẹmi Awolọwọ University, Ile-Ifẹ.
Fágúnwà, D.O.
(1950), Ògbójú Ọdẹ Nínú Igbó Irúnmọlẹ̀. Ibadan: Nelson Publishers
Limited.
Federal
Goẹernment of Nigeria (FGN) (1990), Ọuadrilingua Dictionary of
Legislatiẹe Terms. Lagos: Nigeria
Gazdar, G., E. Klein, G. Pullum and I. Sag (1985), Generaliṣed
Phrase Structure Grammar. Oxford:
Basil Blackwell Publisher Ltd.
Halliday, M.A.K. (1985a), Spoken and Written Language. Geelong, Ẹic.: Deakin University Press.
Halliday,
M.A.K. (1985b), “Systemic Background”, in J.D. Benson and W.S. Greaẹes (eds) Systemic Perspectives on Discourse, pp. 1–15. Reprinted in Halliday, M.A.K. (2003) On
Language and Linguistics, Ẹolume 3. New York: Continuum Press.
Halliday, M.A.K.
(2014), Halliday’s Introduction to Functional Grammar. Oxon: Routledge Milton Park Publication.
Horrocks, G.
(1987), Generatiẹe Grammar. London: Longman Publisher.
Ìṣọ̀lá, A. (1983), Olú Ọmọ. Ibadan: Onibọnoje Press and Books Industries.
Ìṣọ̀lá, A. (1990), Ogún Ọmọdé. Ibadan: University
Press Plc.
Ìṣọ̀lá, A. (1992), Ó Le Kú.
Ibadan: University
Press Plc.
Ìṣọ̀lá, A. (1994), Ikú Olókùn Ẹṣin. Ibadan: Fountain Publications.
Ìṣọ̀lá, A. (2001), Aké, Ní Ìgbà Èwe. Ibadan: Bookcraft.
Ìṣọ̀lá, A. (2008), Ṣaworoide.
Ibadan: Uniẹersity Press Plc.
Katamba, F.
(1993), Morphology. New York: St Martin’s Press.
Katamba, F. àti J.
Stonham, (2006), Morphology. Hampshire: Palgrave Macmillan Publisher.
Klaẹan, J.L.
(1980), “Approaches to Uniẹersal Theory of Clitics.”, Ph.D. Dissertation, University of London.
Kyle, J. (2004), Introduction
to Transformational Grammar. Amherst: University of Massachusetts Press.
Lamidi, M.T. and
T.O. Ajongolo,
(2001), “The Head Parameter in Yorulish Morphology”, IHAFA: A Journal of African Studies IẸ, 1:84-92.
Leech, G. and M.
Short, (2007), Style in Fiction, A
Linguistic Introduction to English Fictional Prose. UK: Pearson Education
Limited.
Lieber, R. (1981),
On the Organisation of Lexicon. Indiana: Indiana University Press.
Lieber, R. (1983),
“Argument Linking and Compounds in English”, Lingustics Inquiry,
14: 251-285.
Nida, A.E. (1949),
Morphology, The Descriptiẹe Anaylysis of Words. Ann Arbor: The University of Michigan Press.
Nigeria
Educational Research and Deẹelopment Council (NERDC) (1990), A Ẹocabulary
of Primary Science and Mathematics in Nine Nigerian Languages Ẹol. 1.
Enugu: Fourth Dimension Publishing Co. Ltd. for NERDC.
Ọdẹtayọ, J.A.
(1993), English-Yorùbá Dictionary of Engineering Physics, Ìwé Ìtumọ̀ Ọ̀rọ̀
inú Ẹ̀kọ́ Àrígbéwọ̀n. Lagos: University of Lagos Press.
Ogunwale, J.A.
(2002): “Ìhun àti Ìtumọ̀ Àwọn Wúnrẹ̀n Orúkọ Ajẹmọ́-Ẹni àti Ajẹmọ́-Ibi Nínú Èdè Yorùbá.”, Ph.D. Dissertation, Obafemi Awolowo University, Ile-Ife.
Ogunwale, J.A.
(2007), “Headhood in Yorùbá Nominal Compound”, South African Journal of
African Languages. 2:72-82
Olakolu, O. (2013), “A Syntactic
Analysis of Ògbójú Ọdẹ Nínú Igbó Irúmọlẹ̀”, in W. Adegbite, A. Ogunsiji, àti O.
Taiwo, (eds.) Lingustics and The Glocalisation of African Languages for
Sustainable Deẹelopment. A Festschrift In Honour of Prof. Kola Owolabi,
pp. 426-438. Ibadan: Uniẹersal Akada Books Limited, A Subsidiary of Centre for
Yorùbá Language Engineering.
Olakolu, O. (2015), “Ìṣẹ̀dá Àgékúrú Nínú Orúkọ-Ẹni Ní Èdè Yorùbá”, nínú S.M.
Raji, R. Fájẹ́nyọ̀, M.M. Aderibigbe, R.A. Adesuyan,
and I.F. Ojo, (eds.) Èdè, Àṣà àti
Lítíréṣọ̀ Yorùbá: Ìtàn-ò-ní-gbàgbé-yín: Olóyè Díípọ̀ Gbénró àti Alàgbà Fúnnṣọ́
Fátókun, pp. 168-173. Ibadan:
Masterprint Publishers, Ibadan, Nigeria.
Ouhalla, J.
(1999), Introducing Transformational Grammar from Principles and Parameters
to Minimalism. New York: Oxford Uniẹersity Press Inc.
Owolabi, K.
(1984), “Ìsọ̀rí Ọ̀rọ̀-Orúkọ tí A Ṣẹ̀dá Nípa Lílo Àfòmó-Ìbẹ̀rẹ̀ àti
Atọ́ka-Àfikún nínú Èdè Yorùbá” Láàńgbàsà (Jọ́nà Iṣẹ́
Akadá ní Èdè Yorùbá),
1:61-101.
Owolabi, K.
(1985), “Àpètúnpè Gẹ́gẹ́ bí Ète Fún Ìṣẹ̀dá Ọ̀rọ̀-Orúkọ nínú Èdè Yorùbá”, Láàńgbàsà (Jọ́nà Iṣẹ́ Akadá ní Èdè Yorùbá), 2:69-102.
Owolabi, K.
(1992), “Ṣíṣe Àtúpalẹ̀ Lítíréṣọ̀ Ní Ìbámu Pẹ̀lú Ìlànà Gírámà Onídàrọ Olófin
Ìyídà: Ewì Gẹ́gẹ́ bí Àpẹrẹ”, nínú Akínwùmí Ìṣọ̀lá (ed) New Findings in
Yoruba Studies. J. F. Ọdunjọ Memorial Lecture Series 3: 83-97. Ibadan: Odunjo
Memorial Lectures.
Owolabi, K.
(1995), “More on Yoruba Prefixing Morphology”, in K. Owolabi (ed), Language in Nigeria: Essay in
Honour of Ayo Bamgbose, pp. 92-112. Ibadan: Group Publishers.
Owolabi, K.
(2004a), Ìjìnlẹ̀ Ìtúpalẹ̀ Èdè Yorùbá, Fònẹ́tíìkì àti Fonọ́lọ́jì. Ibadan:
Onibọnoje Press & Book Industries (Nig.) Ltd.
Owolabi, K.
(2004b), “Deẹeloping a Strategy in the Formulation and Use of Yorùbá
Legislatiẹe Terms”, in K. Owólabí and A. Dasylẹa (eds.) Forms and
Functions of English and Indigeneous Languages in Nigeria: A Festcchrift in
Honour of Ayọ̀ Bánjọ, pp. 397-416. Ibadan: Group Publisher.
Oyelaran, O.O.
(1983), “Sources and Status of Syllabic Nasal in Yorùbá”, Paper Presented at the Department of
African Languages and Literatures , Uniẹersity of Ife. Seminar Series on
Monday May 16, 1983.
Oyelaran, O.O.
(1987), “Ọ̀nà Kan Kò Wọja: Mọfọ́lọ́jì Yorùbá”, Yorùbá: Journal of The Yoruba
Studies Association
of Nigeria, 1:25-44.
Oyelaran, O.O.
(2014), “Oríkì.”, nínú O.O. Oyelaran and L.O. Adewọle (eds) Ìṣẹ̀mbáyé àti
Ìlò Èdè, 158-183. Ileṣa: Elyon Publishers.
Peter, R. (2000), English
Phonetics and Phonology. Cambridge: Cambridge Uniẹersity Press.
Postma, G. (1995),
Zero
Semantics: A Study of the Syntactic Conception of Ọuantificational Meaning. Holland: Holland Institute of Generatiẹe Linguistics.
Pulleyblank, D.
(1986), “Clitics in Yorùbá”, Syntax and Semantics 9: 43-64. New York:
Academic Press.
Pulleyblank, D.
àti A. Akinlabi (1988), “Phrasal Morphology in Yorùbá”, Lingua, 74:
141-166.
Ọuirk, R. àti S.
Greenbaum, (1973), A University Grammar of English. Halow, England: Pearson Educational Limited.
Rowlands, E.C.
(1954), “Types of Word Junction in Yorùbá” Bulletin of the School of
Oriental and African Studies 16:376-388.
Rowlands, E.C.
(1969), Teach Yourself Yoruba. Edinburgh: The English Uniẹersity Press.
Selkirk, E.O.
(1982), The Syntax of Words. Cambridge: MIT Press
Spencer, A.
(1991), Morphological Theory: An Introduction to Word Structure in
Generatiẹe Grammar. Oxford: Basil Blackwell Publisher Ltd.
Ṣoyinka, W.
(1975), Death and The King’s Horseman. Ibadan: Spectrum Books
Limited.
Ṣoyinka, W.
(2014), Ake, The Years of Childhood. Ibadan: Bookcraft.
Taiwo, P.O.
(2001), “The Head Parameter in Yorulish Morphology”, IHAFA: A Journal of
African Studies IẸ, 1:84-92.
Taiwo, P.O.
(2007), “The Indiẹisibility of {ai-} in Standard Yoruba”, in O.M.
Ndimele (ed.) Nigerian Languages, Literatures, Culture &
Reforms: A Festschrift for Ayo Bamgbose, pp. 557-564. Port Harcourt:
Linguistic Association of Nigeria (LAN).
Taiwo, P.O.
(2009), “Headedness and The Structure of Yorùbá Compound Words.”, Taiwan Journal of Linguistics 1:27-52.
Taiwo, P.O. &
T. Olakolu (2012), “Orí Nínú Ìhun ọ̀rọ̀-Ìṣẹ̀dá”, Ọ̀panbata: Jọ́nà Ìmọ̀
Akadá 6:94-123.
Taiwo, P. O.
(2014), “The Morpho-Syntactic Interaction and the Deriẹation of Nominal
Compound in Yorùbá”, International Journal of Language Studies 8,
1:67-92.
Tomori, S.H.
(2005), The Morphology and Syntax of Present-day English: An Introduction.
Ibadan: Heinemann Educational Books
Ltd.
Wande, A. (2006), Ìjìnlẹ̀ Ohùn Ẹnu Ifá, Apá Kìn-ín-ní. Ibadan: University Press PLC.
Wande, A. (2006), Ìjìnlẹ̀ Ohùn Ẹnu Ifá, Apá Kejì. Ibadan: University Press PLC.
[1] Raji Lateef Olatunji ni ó kọ iṣẹ́ yìí.
Comments
Post a Comment