Posts

Showing posts from March, 2021

WAYS OF STUDYING LINGUSTICS

Although there are many ways of studying language, most approaches belong to one of the two main branches of linguistics: descriptive linguistics and comparative linguistics. DESCRIPTIVE LINGUISTICS  Descriptive linguistics is the study and analysis of spoken language. The techniques of descriptive linguistics were devised by German American anthropologist Franz Boas and American linguist and anthropologist Edward Sapir in the early 1900s to record and analyze Native American languages. Descriptive linguistics begins with what a linguist hears native speakers say. By listening to native speakers, the linguist gathers a body of data and analyzes it in order to identify distinctive sounds, called phonemes. Individual phonemes, such as /p/ and /b/, are established on the grounds that substitution of one for the other changes the meaning of a word. After identifying the entire inventory of sounds in a language, the linguist looks at how these sounds combine to create morphemes, or unit...

ÀLÀYÉ RÁŃPẸ́ LÓRÍ IṢẸ́ Ọ̀JỌ̀GBỌ́N SALAWU S. A (2002) TÍ WỌ́N PÈ NÍ : The Morphological source of ÀÌ- as a Negation nominalization form in Yoruba: A dialectological analysis.

  ÌFÁÀRÀ Ohun tí a fẹ́ ṣe nínú iṣẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n S. A Salawu tí wọ́n pè ní _ The Morphological source of ÀÌ- as a Negation nominalization form in Yoruba: A dialectological analysis. _ni ọdún 2002 ni ṣíṣe àlàyé iṣẹ́ ni ṣókí pẹ̀lú èdè Yorùbá.  👉 Àwọn ohùn tí ó ṣe kókó jù lọ nípa iṣẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n náà nìwọ̀nyí :👇 1. Ète iṣẹ́ akadá náà 2. Tíọ̀rì Gírámà tí Ọ̀jọ̀gbọ́n náà mú lò. 3. Ìgbésẹ̀ Mofoloji lédè Yorùbá 4. Mọ́fíìmù {àì-} 5. Ìwòye àwọn onímọ̀ gírámà èdè Yorùbá àtijọ́ lórí Mọ́fíìmù {àì-} 6. Ìwòye O. Awobuluyi (1978) lórí Mọ́fíìmù {àì-}. 7. Ìwòye S. Adewole (1992) lórí Mọ́fíìmù {àì-} 8. Ìwòye O. Solomon (1983) lórí Mọ́fíìmù {àì-} 8. Fífi ojú ẹ̀ka-èdè wo Mọ́fíìmù {àì-} Àwọn kókó wọ̀nyí ni a ó fi ṣe àlàyé iṣẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n náà.  Ní ìsonísókí 👉 Àwọn onímọ̀ àtijó bí Bámgbóṣé, Olowookere gbà pé mọ́fíìmù kàn ṣoṣo ni { àì- }. Awobuluyi (1978) gbà pé mọ́fíìmù ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni { àì- } {à-, ì-} ní. Ṣùgbọ́n { ì- } ló ń ṣiṣẹ́ Ìyísódì. Bí àpẹẹrẹ : àlọ = àìlọ(Neg)  Adewole(1992) gbà pé ...

HOW LANGUAGE AND LINGUISTCS RELATE

Linguistics is the scientific study of language. Several of the subfields of linguistics that will be discussed here are concerned with the major components of language: Phonetics is concerned with the sounds of languages, phonology with the way sounds are used in individual languages, morphology with the structure of words, syntax with the structure of phrases and sentences, and semantics with the study of meaning. Another major subfield of linguistics, pragmatics, studies the interaction between language and the contexts in which it is used. Synchronic linguistics studies a language's form at a fixed time in history, past or present. Diachronic, or historical, linguistics, on the other hand, investigates the way a language changes over time. A number of linguistic fields study the relations between language and the subject matter of related academic disciplines, such as sociolinguistics (sociology and language) and psycholinguistics (psychology and language). In principle, applie...

WHAT LANGUAGE IS

  Introduction Language , the principal means used by human beings to communicate with one another. Language is primarily spoken, although it can be transferred to other media, such as writing. If the spoken means of communication is unavailable, as may be the case among the deaf, visual means such as sign language can be used. A prominent characteristic of language is that the relation between a linguistic sign and its meaning is arbitrary: There is no reason other than convention among speakers of English that a dog should be called dog, and indeed other languages have different names (for example, Spanish perro, Russian sobaka, Japanese inu). Language can be used to discuss a wide range of topics, a characteristic that distinguishes it from animal communication. The dances of honey bees, for example, can be used only to communicate the location of food sources (see Honey Bee: Communication). While the language-learning abilities of apes have surprised many—and there continues to...

Àgbéyèwo èrò Samuel Àjàyí Crowther lórí ọ̀rọ̀-Orúkọ lédè Yorùbá

Ta ni Rev Samuel Ajayi Crowther?  Ọmọ bíbí ìlú Oṣoogun ní ìpínlè Ọ̀yọ́ ni Crowther. A bí Crowther ni ọdún 1809,Crowther sì di olóògbé ni ọdún 1891. Ọ̀kan lára àwọn ọmọ ilẹ̀ Yorùbá tí àwọn Òyìnbó aláwọ̀ funfun kó lẹ́rú lásìkò òwò ẹrú ni Crowther. Onímọ̀ èdè Yorùbá ni Crowther. Ajayi Crowther ni ẹni àkọ́kọ́ tí ó kọ́kọ́ gbìyànjú láti kọ èdè Yorùbá sílẹ̀ ní ọdún 1843. Crowther ṣe àkọsílẹ̀ ìwé Lúùkù 1:36 ní èdè Yorùbá, ó sì kọ ọ́ ní ọdún náà báyìí: ohung ohwor tí aobih ní inoh reh li aomakpe li ọmọh Ọlọrung ; èyí tí àkọtọ́ òde-òní gbé e kalẹ báyìí : ohun ọ̀wọ̀ tí a ó bí ní inú rẹ ni a ó máa pè ní ọmọ Ọlọ́run.  Crowther ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ lórí èdè Yorùbá ṣùgbọ́n èyí tí a ó gbé yẹ̀ wò báyìí ni èrò rẹ̀ lórí ọ̀rọ̀-Orúkọ lédè Yorùbá. Àgbéyèwo tí a ó ṣe lórí èrò rẹ̀ ni pé, ṣé èrò rẹ̀ lórí ọ̀rọ̀-Orúkọ lédè Yorùbá tọ̀nà? Bí kò bá sì tọ̀nà, kín ni àwíjàre wá lórí àìtọ̀nà èrò rẹ̀. Wàyí o, ẹ jẹ́ kí á bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ náà ni pẹrẹu. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé èdè Gẹ̀ẹ́sì ni Crowther fi gbé iṣẹ́ rẹ̀ náà kalẹ̀...